Orin Dafidi 136:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó mú àwọn eniyan rẹ̀ la aṣálẹ̀ já,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae;

Orin Dafidi 136

Orin Dafidi 136:15-25