Orin Dafidi 130:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Bí OLUWA bá ń sàmì ẹ̀ṣẹ̀,ta ló lè yege?

4. Ṣugbọn ní ìkáwọ́ rẹ ni ìdáríjì wà,kí á lè máa bẹ̀rù rẹ.

5. Mo gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, àní, mo gbé ọkàn mi lé e,mo sì ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ̀.

Orin Dafidi 130