Orin Dafidi 130:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA!

2. OLUWA, gbóhùn mi,dẹtí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.

3. Bí OLUWA bá ń sàmì ẹ̀ṣẹ̀,ta ló lè yege?

Orin Dafidi 130