Orin Dafidi 126:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ń gbé irúgbìn lọ sí oko tẹkúntẹkún,yóo ru ìtí ọkà pada sílé tayọ̀tayọ̀.

Orin Dafidi 126

Orin Dafidi 126:1-6