Orin Dafidi 125:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Eniyan burúkú kò ní ní àṣẹlórí ilẹ̀ àwọn olódodo,kí àwọn olódodo má baà dáwọ́ lé ibi.

4. OLUWA, ṣe oore fún àwọn eniyan rere,ati fún àwọn olódodo.

5. Ṣugbọn OLUWA yóo fi irú ìyà àwọn aṣebi jẹàwọn tí ó yà sí ọ̀nà àìtọ́.Alaafia fún Israẹli!

Orin Dafidi 125