Orin Dafidi 121:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Mo gbójú sókè wo àwọn òkè,níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi ti ń wá?

2. Ìrànlọ́wọ́ mi ń ti ọ̀dọ̀ OLUWA wá,ẹni tí ó dá ọ̀run ati ayé.

Orin Dafidi 121