Orin Dafidi 120:6-7 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Ó pẹ́ jù tí mo tí ń bá àwọn tí ó kórìíra alaafia gbé.

7. Alaafia ni èmi fẹ́,ṣugbọn nígbà tí mo bá sọ̀rọ̀, ìjà ṣá ni tiwọn.

Orin Dafidi 120