Orin Dafidi 119:172-175 BIBELI MIMỌ (BM)

172. N óo máa fi ọ̀rọ̀ rẹ ṣe orin kọ,nítorí pé gbogbo òfin rẹ ni ó tọ̀nà.

173. Múra láti ràn mí lọ́wọ́,nítorí pé mo ti gba ẹ̀kọ́ rẹ.

174. Ọkàn mi ń fà sí ìgbàlà rẹ, OLUWA;òfin rẹ sì ni inú dídùn mi.

175. Dá mi sí kí n lè máa yìn ọ́,sì jẹ́ kí òfin rẹ ràn mí lọ́wọ́.

Orin Dafidi 119