Orin Dafidi 119:102-105 BIBELI MIMỌ (BM)

102. N kò yapa kúrò ninu òfin rẹ,nítorí pé o ti kọ́ mi.

103. Ọ̀rọ̀ rẹ dùn mọ́ mi pupọ,ó dùn ju oyin lọ.

104. Nípa ẹ̀kọ́ rẹ ni mo fi ní òye,nítorí náà mo kórìíra gbogbo ìwà èké.

105. Ọ̀rọ̀ rẹ ni àtùpà fún ẹsẹ̀ mi,òun ni ìmọ́lẹ̀ sí ọ̀nà mi.

Orin Dafidi 119