Orin Dafidi 116:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Mo fẹ́ràn OLUWA nítorí pé ó gbọ́ adura ati ẹ̀bẹ̀ mi.

2. Nítorí pé ó tẹ́tí sí mi,nítorí náà, n óo máa ké pè éníwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè.

3. Tàkúté ikú yí mi ká;ìrora isà òkú dé bá mi;ìyọnu ati ìnira sì bò mí mọ́lẹ̀.

Orin Dafidi 116