Orin Dafidi 108:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ọkàn mi dúró ṣinṣin, Ọlọrunọkàn mi dúró ṣinṣin.N óo kọrin, n óo sì máa yìn ọ́.Jí, ìwọ ọkàn mi!

2. Ẹ jí ẹ̀yin ohun èlò ìkọrin ati hapu!Èmi fúnra mi náà yóo jí ní òwúrọ̀ kutukutu,

Orin Dafidi 108