Orin Dafidi 106:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA!Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeunnítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

2. Ta ló lè sọ iṣẹ́ agbára OLUWA tán?Ta ló sì lè fi gbogbo ìyìn rẹ̀ hàn?

3. Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ń ṣe ẹ̀tọ́,àwọn tí ń ṣe ohun tí ó tọ̀nà nígbà gbogbo.

Orin Dafidi 106