Orin Dafidi 101:6 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo máa fi ojurere wo àwọn olóòótọ́ ní ilẹ̀ náà,kí wọ́n lè máa bá mi gbé;ẹni tí ó bá sì ń hu ìwà pípé ni yóo máa sìn mí.

Orin Dafidi 101

Orin Dafidi 101:5-8