Ọbadaya 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olùgbàlà yóo lọ láti Sioni,wọn yóo jọba lórí òkè Edomu;ìjọba náà yóo sì jẹ́ ti OLUWA.”

Ọbadaya 1

Ọbadaya 1:14-21