Nọmba 6:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA sọ fún Mose kí ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé,

2. “Nígbà tí ọkunrin tabi obinrin kan bá ṣe ìlérí láti di Nasiri, tí ó sì ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ fún OLUWA,

Nọmba 6