Nọmba 33:26-30 BIBELI MIMỌ (BM) Láti Makihelotu wọ́n lọ sí Tahati. Láti Tahati wọ́n lọ sí Tẹra. Láti Tẹra wọ́n lọ sí Mitika. Láti