Nọmba 33:23-26 BIBELI MIMỌ (BM)

23. Láti Kehelata wọ́n lọ sí Òkè Ṣeferi.

24. Láti Òkè Ṣeferi wọ́n lọ sí Harada.

25. Láti Harada wọ́n lọ sí Makihelotu.

26. Láti Makihelotu wọ́n lọ sí Tahati.

Nọmba 33