Nọmba 33:23-25 BIBELI MIMỌ (BM)

23. Láti Kehelata wọ́n lọ sí Òkè Ṣeferi.

24. Láti Òkè Ṣeferi wọ́n lọ sí Harada.

25. Láti Harada wọ́n lọ sí Makihelotu.

Nọmba 33