Nọmba 32:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, ẹ̀yin ìran ẹlẹ́ṣẹ̀ yìí dìde gẹ́gẹ́ bí àwọn baba ńlá yín láti mú kí inú bí OLUWA gidigidi sí Israẹli.

Nọmba 32

Nọmba 32:5-19