Nọmba 31:44-46 BIBELI MIMỌ (BM) Ẹgbaa mejidinlogun (36,000) mààlúù. Ẹgbaa mẹẹdogun ó lé ẹẹdẹgbẹta (30,500) kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.