Nọmba 10:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA sọ fún Mose pé,

2. “Fi fadaka tí wọ́n fi òòlù lù ṣe fèrè meji fún pípe àwọn ọmọ Israẹli jọ ati títú ibùdó palẹ̀.

Nọmba 10