Nehemaya 7:49-52 BIBELI MIMỌ (BM)

49. àwọn ọmọ Hanani, àwọn ọmọ Gideli, ati àwọn ọmọ Gahari,

50. àwọn ọmọ Reaaya, àwọn ọmọ Resini, ati àwọn ọmọ Nekoda,

51. àwọn ọmọ Gasamu, àwọn ọmọ Usa, ati àwọn ọmọ Pasea,

52. àwọn ọmọ Besai, àwọn ọmọ Meuni, ati àwọn ọmọ Nefuṣesimu,

Nehemaya 7