Nehemaya 7:31-34 BIBELI MIMỌ (BM)

31. Àwọn ará Mikimaṣi jẹ́ mejilelọgọfa (122).

32. Àwọn ará Bẹtẹli ati Ai jẹ́ mẹtalelọgọfa (123).

33. Àwọn ará Nebo keji jẹ́ mejilelaadọta.

34. Àwọn ọmọ Elamu keji jẹ́ ẹgbẹfa ó lé mẹrinlelaadọta (1,254).

Nehemaya 7