Nehemaya 7:24-26 BIBELI MIMỌ (BM)

24. Àwọn ọmọ Harifi jẹ́ aadọfa ó lé meji (112).

25. Àwọn ọmọ Gibeoni jẹ́ marundinlọgọrun-un.

26. Àwọn ará Bẹtilẹhẹmu ati Netofa jẹ́ ọgọsan-an ó lé mẹjọ (188).

Nehemaya 7