Nehemaya 12:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Orúkọ àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n bá Serubabeli ọmọ Ṣealitieli ati Jeṣua dé nìwọ̀nyí: Seraaya, Jeremaya ati Ẹsira,

2. Amaraya, Maluki, ati Hatuṣi,

3. Ṣekanaya, Rehumu, ati Meremoti,

4. Ido, Ginetoi, ati Abija,

Nehemaya 12