Mika 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi ni mo sá mu yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti, tí mo rà yín pada kúrò lóko ẹrú; tí mo rán Mose, Aaroni ati Miriamu láti ṣáájú yín.

Mika 6

Mika 6:3-8