Matiu 24:14 BIBELI MIMỌ (BM)

A óo waasu ìyìn rere ìjọba yìí ní gbogbo ayé gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí sí gbogbo orílẹ̀-èdè. Lẹ́yìn náà ni òpin yóo dé.

Matiu 24

Matiu 24:4-15