Matiu 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnìkan bá bi yín ní nǹkankan, ẹ dá a lóhùn pé, ‘Oluwa nílò wọn.’ Lẹsẹkẹsẹ wọn yóo jẹ́ kí ẹ mú wọn wá.”

Matiu 21

Matiu 21:1-4