Luku 9:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Jesu pe àwọn mejila jọ. Ó fún wọn ní agbára ati àṣẹ láti lé gbogbo ẹ̀mí èṣù jáde ati láti ṣe ìwòsàn oríṣìíríṣìí àìsàn.

2. Ó rán wọn láti waasu ìjọba Ọlọrun ati láti ṣe ìwòsàn.

Luku 9