Luku 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn amòfin ati àwọn Farisi ń ṣọ́ Jesu bí yóo ṣe ìwòsàn ní Ọjọ́ Ìsinmi kí wọ́n lè rí ẹ̀sùn fi kàn án.

Luku 6

Luku 6:1-9