Luku 22:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan dá iná sáàrin agbo-ilé, wọ́n jókòó yí i ká, Peteru náà wà láàrin wọn.

Luku 22

Luku 22:47-56