Luku 2:30-32 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Nítorí ojú mi ti rí ìgbàlà rẹ,

31. tí o ti pèsè níwájú gbogbo eniyan;

32. ìmọ́lẹ̀ láti fi ọ̀nà han àwọn kèfèríati ògo fún Israẹli, eniyan rẹ.”

Luku 2