Luku 18:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Adájọ́ kan wà ní ìlú kan tí kò bẹ̀rù Ọlọrun, tí kò sì ka ẹnikẹ́ni sí.

Luku 18

Luku 18:1-12