Luku 1:73-75 BIBELI MIMỌ (BM)

73. gẹ́gẹ́ bí ó ti búra fún Abrahamu baba wa,

74. pé yóo gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa,ati pé yóo fún wa ní anfaani láti máa sìn ín láì fòyà,

75. pẹlu ọkàn kan ati pẹlu òdodoníwájú rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ ayé wa.

Luku 1