Lefitiku 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí alufaa sun wọ́n lórí pẹpẹ náà gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun olóòórùn dídùn. Ti OLUWA ni gbogbo ọ̀rá ẹran.

Lefitiku 3

Lefitiku 3:6-17