Lefitiku 27:23 BIBELI MIMỌ (BM)

alufaa yóo ṣírò iye tí ilẹ̀ náà bá tó títí di ọdún Jubili, ẹni náà yóo sì san iye rẹ̀ ní ọjọ́ náà bí ohun ìyàsọ́tọ̀ fún OLUWA.

Lefitiku 27

Lefitiku 27:14-30