Lefitiku 18:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA ní kí Mose, sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.