Lefitiku 17:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA sọ fún Mose pé

2. kí ó sọ fún Aaroni, ati àwọn ọmọkunrin rẹ̀, ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli pé, “Ohun tí OLUWA paláṣẹ nìyí:

Lefitiku 17