Lefitiku 15:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹnikẹ́ni tí ó bá fara kan ibùsùn rẹ̀, fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀; yóo jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Lefitiku 15

Lefitiku 15:11-31