Kronika Kinni 9:41-44 BIBELI MIMỌ (BM)

41. Mika bí ọmọkunrin mẹrin: Pitoni, Meleki, Tarea ati Ahasi;

42. Ahasi sì bí Jara. Jara bí ọmọ mẹta: Alemeti, Asimafeti ati Simiri, Simiri bí Mosa,

43. Mosa sì bí Binea. Binea ni baba Refaaya, Refaaya ni ó bí Eleasa, Eleasa sì bí Aseli.

44. Aseli bí ọmọkunrin mẹfa: Asirikamu, Bokeru, ati Iṣimaeli, Ṣearaya, Ọbadaya, ati Hanani.

Kronika Kinni 9