Kronika Kinni 7:39-40 BIBELI MIMỌ (BM) Ula bí: Ara, Hanieli ati Risia. Àwọn ni ìran Aṣeri, wọ́n jẹ́ baálé baálé ni ìdílé baba wọn