Kronika Kinni 7:26-28 BIBELI MIMỌ (BM)

26. baba Ladani, baba Amihudu, baba Eliṣama;

27. baba Nuni, baba Joṣua.

28. Àwọn ilẹ̀ ìní wọn ati àwọn agbègbè tí wọ́n tẹ̀dó sí nìwọ̀nyí: Bẹtẹli, Naarani ní apá ìlà oòrùn, Geseri ní apá ìwọ̀ oòrùn, Ṣekemu ati Aya; pẹlu àwọn ìletò tí ó wà lẹ́bàá àyíká wọn.

Kronika Kinni 7