Kronika Kinni 7:24-26 BIBELI MIMỌ (BM)

24. Efuraimu ní ọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Ṣeera, òun ló kọ́ ìlú Beti Horoni ti òkè ati ti ìsàlẹ̀, ati Useni Ṣeera.

25. Orúkọ àwọn ọmọ ati arọmọdọmọ Efuraimu yòókù ni Refa, baba Reṣefu, baba Tela, baba Tahani;

26. baba Ladani, baba Amihudu, baba Eliṣama;

Kronika Kinni 7