Kronika Kinni 6:17-21 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Àwọn ọmọ Geriṣoni ni: Libini ati Ṣimei.

18. Àwọn ọmọ Kohati ni: Amramu, Iṣari, Heburoni, ati Usieli.

19. Àwọn ọmọ Merari ni: Mahili ati Muṣi. Àwọn ni baba ńlá àwọn ọmọ Lefi.

20. Àwọn tí wọ́n ṣẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Geriṣoni nìwọ̀nyí: Libini ni baba Jahati, Jahati bí Sima,

21. Sima bí Joa, Joa bí Ido, Ido bí Sera, Sera sì bí, Jeaterai.

Kronika Kinni 6