Kronika Kinni 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsira bí Jeteri, Meredi, Eferi, ati Jaloni. Meredi fẹ́ Bitia, ọmọbinrin Farao. Wọ́n bí ọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Miriamu ati ọmọkunrin meji: Ṣamai ati Iṣiba.

Kronika Kinni 4

Kronika Kinni 4:9-20