Kronika Kinni 29:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Dafidi yin OLUWA níwájú gbogbo eniyan, ó ní: “Ìyìn ni fún ọ títí lae, OLUWA, Ọlọrun Israẹli, Baba ńlá wa,

Kronika Kinni 29

Kronika Kinni 29:4-12