Kronika Kinni 2:41-43 BIBELI MIMỌ (BM)

41. Ṣalumu bí Jekamaya, Jekamaya sì bí Eliṣama.

42. Àwọn ọmọ Kalebu, arakunrin Jerameeli, nìwọ̀nyí: Mareṣa, baba Sifi ni àkọ́bí rẹ̀. Lẹ́yìn náà, ó bí Heburoni.

43. Heburoni bí ọmọ mẹrin: Kora, Tapua, Rekemu ati Ṣema.

Kronika Kinni 2