Kronika Kinni 2:10-13 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Ramu bí Aminadabu, Aminadabu bi Naṣoni, olórí pataki ninu ẹ̀yà Juda,

11. Nahiṣoni ni baba Salima; Salima ni ó bí Boasi,

12. Boasi bí Obedi, Obedi sì bí Jese.

13. Jese bí ọmọ meje; orúkọ wọn nìyí bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn: Eliabu ni àkọ́bí, lẹ́yìn náà Abinadabu ati Ṣimea;

Kronika Kinni 2