Kronika Kinni 15:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi pe Sadoku ati Abiatari, àwọn alufaa, pẹlu àwọn olórí àwọn ọmọ Lefi mẹfa, Urieli, Asaaya, ati Joẹli, Ṣemaaya, Elieli, ati Aminadabu,

Kronika Kinni 15

Kronika Kinni 15:10-20