Kronika Kinni 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi kọ́ ọpọlọpọ ilé fún ara rẹ̀ ní ìlú Dafidi. Ó tọ́jú ibìkan fún Àpótí Majẹmu Ọlọrun. Ó sì pa àgọ́ lé e lórí.

Kronika Kinni 15

Kronika Kinni 15:1-10